Recent Scheme of Work on Yoruba Language

Syllabus for Lower Basic




FIRST TERM
BASIC 1 BASIC 2 BASIC 3
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Dida orúkọ nnkan inu kilaase

Sub-Topic:
Content:
Daruko nnkan bii aga, tàbìlì, pata kò akowé, àwòrán ara ògiri, abbi
WEEK 2

Theme: ÈDÈ

Topic: Ojuse (ebi/idile)

Sub-Topic:
Content:
1. Ojuse omo na gbale, fo abo,je ise ti won ba ran an, bowo fun obi ati gbogbo awon to ju lo
2. obi: pese ile gbigbe, san owo ile iwe, ra aso fun omo,pese iwosan nigba aisan aab to peye wa ounje
3. egbom: se itoju aburo re daabo oo abbl
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìtàkurọ̀sọ siwaju sii

Sub-Topic:
Content:
1. Ìtàkurọ̀ sọ lori aabo opopona oko.
2. Lilo afara idatiti koja
3. Wiwo otun, wo osi, tun otun wo ki o to soda titi
4. Ririn ni apa osi
5. Ririn pelu akiyesara
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Dida orúkọ nnkan inu kilaase (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Daruko nnkan bii aga, tàbìlì, pata kò akowé, àwòrán ara ògiri, abbi
WEEK 3

Theme: ÈDÈ

Topic: Itesiwaju ninu didaruko nnkan

Sub-Topic:
Content:
1. Oruko awon nnkan to wa ni ayika akekoo Ile- telifison redi, beedi, aga, abbl Ile eko- efun, aga ati tanilli rula,biro, abbl Opopona Oja- moto enyika, keke, igi abbl Oja- ata, isu, eso, elubo, eran, eja, abbl
2. Iwulo awon ohun ti a ti daruko
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ònká siwaju sii (51-100)

Sub-Topic:
Content:
1. Onka yorùbá lati ookanlelaadota de ogorunun
2. Arọ́pò/ayokuro awon onka kan lati fun wa ni onka miiran
3. Titoka si awon oro to se pataki fun onka (le ati din)
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Sise nnkan

Sub-Topic:
Content:
Dide duro,jokoo,wa, jade, wole, dákẹ́, patèwo, abbl
WEEK 4

Theme: ÈDÈ

Topic: Itesiwaju sise nnkan

Sub-Topic:
Content:
1. awon ohun elo ise ile kekeke bii: igbale,kainkan, ose, garawa-iponmim, ife, abbl
2. Awon ise ile kekeke:gbale, bu omi, fo abo, ponmi
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Didaruko nnkan siwaju sii

Sub-Topic:
Content:
Oruko awon nnkan to wa ni aarin ilu b.a. oja, ile-iwosan, ile-itaja nla ati kekeke ni orisiirisii, àafin oba, ago, olopaa, papa isere nla, ileiwe lorisiirisii, abbl
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Sise nnkan (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Dide duro,jokoo,wa, jade, wole, dákẹ́, patèwo, abbl
WEEK 5

Theme: ÈDÈ

Topic:
1. Itesiwaju ninu ìtàkurọ̀sọ
2. Onka Ookanla de aadota (11-50)

Sub-Topic:
Content:
A. Itesiwaju ninu ìtàkurọ̀sọ
Oruko eni ti o n pade fun igba akoko,ilu re, ojo ori re, ile iwe ti o n lo n

B. Onka Ookanla de aadota (11-50)
1. Kika onka lati ookanla de aadota
2. Sise idamo figo ookanla de aadota
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Siso nnkan siwaju sii

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii ise owo ati ise ona b.a. aworan yiya, eni hihun, idi igbale hihun, awo/aso riran, ere gbigbe, igba finfin, abbl
2. Awon ohun elo fun awon ise wonyi
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìsọ̀ rọ̀gbèsì laarin akekoo

Sub-Topic:
Content:
1. Beere oruko akekoo
2. níkí akekoo so ojo ori re
WEEK 6

Theme: ÈDÈ

Topic: Itesiwaju ninu kika alufabeeti

Sub-Topic:
Content:
1. kiko alifabeeti yoruba si ara patako ikowe
2. Sise afihan faweli alifabeeti yoruba
3. Kiko konsonanti si oju patako ikowe
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: kiko silebu

Sub-Topic:
Content:
Oro onisilebu kan b.a K + F
D + e = de
W+ a = wa
J + e = je
2. Oro onisilebu meji b.a F + KF
A + de = ade
I + ku = iku
I + lu = ilu
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìsọ̀ rọ̀gbèsì laarin akekoo

Sub-Topic:
Content:
1. Beere oruko obi akekoo
2. Beere oruko ilu akekoo, abbl
WEEK 7

Theme: ÈDÈ

Topic: Kika silebu

Sub-Topic:
Content:
1. Alaye ohun ti silebu je (ege oro)
2. baba = ba ba
Bata = ba ta
Kekere = ke ke re
Patapata = pa tra pa ta
Iya = i ya
Elegede = e le ge de
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kiko gbolohun keekeeke (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
kiKo awon gbolohun keekeeke B.a. Bade lo si ile iwe;
Ayo age igi;
Temitope mo iwe
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka 1-100

Sub-Topic:
Content:
1. kin ni onka?
2. ilo onka
WEEK 8

Theme: ÈDÈ

Topic: Itesiwaju ninu kiko alufabeeti

Sub-Topic:
Content:
kiko alifabeeti si oju patako ikowe
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kiko gbolohun keekeeke

Sub-Topic:
Content:
kiKo awon gbolohun keekeeke B.a. Bade lo si ile iwe;
Ayo age igi;
Temitope mo iwe
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka 1-100

Sub-Topic:
Content:
1. kika onka
2. Sise ìdámọ̀ figo onka
WEEK 9

Theme: ÈDÈ

Topic: Kiko silebu

Sub-Topic:
Content:
1. Alaye ohun ti silebu je (ege oro)
2. Eja = E ja
Eku = E ku
Ilu = I lu
Ewure = E wu re
Agolo = A go lo
Abbl
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Sipeli oro

Sub-Topic:
Content:
Kiko oro Yoruba keekeeke , b.a aga.Tabilli, iwe, eye, oju ese, owo, ori, imu, aye

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION
SECOND TERM
BASIC 1 BASIC 2 BASIC 3
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Saaju Kika álúfábẹ́ ẹ̀tì

Sub-Topic:
Content:
Aja, aga, ologbo, bata , igi, ewure, eja, abbl
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Ere onise onijolorin

Sub-Topic:
Content:
1. kiko orin
2. ijo jijo
3. ifasaroro
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Ere Onitan kekere

Sub-Topic:
Content:
1. Kika ere onise
2. sise ere onise
3. Ijiriri lori eko ti a ri ko ati eda inu itan
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Saaju Kika álúfábẹ́ ẹ̀tì (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Aja, aga, ologbo, bata , igi, ewure, eja, abbl
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Ere onise onijolorin (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. ijupajuse
2. orin iyawo n lota ekun meran, eye, meloo tolongo waye, abbl
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Ere Onitan kekere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika ere onise
2. sise ere onise
3. Ijiriri lori eko ti a ri ko ati eda inu itan
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kika alifabeeti

Sub-Topic:
Content:
Kiko álúfábẹ́ẹ̀tì yorubá sara pata ko ikowetg
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Owe kekeke

Sub-Topic:
Content:
Awon owe kekeke: bami na omo mi, ko denu olomo, maluu, ti, ko ni iru oluwa io n ba a le Esinsin owe lesin oro, oro, lesin, owe bi oro ba sonu, owe la fi n wa a
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Orin omode siwaju sii

Sub-Topic:
Content:
awon orin ati eko ti won ko wa: b.a. kini n o fole se laye ti mo wa….
Imototo lo le segun orun gbogbo….
We ki o mo, ge eekanna re, jeun to dara
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kika alifabeeti (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Kiko álúfábẹ́ẹ̀tì yorubá sara pata ko ikowetg
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Owe kekeke (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Awon owe kekeke: bami na omo mi, ko denu olomo, maluu, ti, ko ni iru oluwa io n ba a le Esinsin owe lesin oro, oro, lesin, owe bi oro ba sonu, owe la fi n wa a
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Owe siwaju sii

Sub-Topic:
Content:
1. Owe ati Pataki re
2. Titumo owe ati liloo loro b.a. Agboju le ogun fi ara re fosi ta.Owo omode ko to pepe, tagbalagba ko wo kenge agba kii wa loja kori omo tuntun wo
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: Saaju Kiko álúfábẹ́ ẹ̀tì yoruba

Sub-Topic:
Content:
Aja, boolu, doje, eku, elede, gbaguuda, abbl
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Owe kekeke (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Bi omode se n pa owe niwaju agba
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Alo apamo

Sub-Topic:
Content:
1. Alo apamo kii ni orin
2. maa n je ibeere ati idahun b.a.kinlo kan Oba nikoo? = Abe
3. Maa n weye saaju alo onitan
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Saaju Kiko álúfábẹ́ ẹ̀tì yoruba (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Aja, boolu, doje, eku, elede, gbaguuda, abbl
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Alo onitan

Sub-Topic:
Content:
Alo onitan: alo ijapa alo olorogun,alo olorun, alo alailorin
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Alo apamo

Sub-Topic:
Content:
1. Alo apamo kii ni orin
2. maa n je ibeere ati idahun b.a.kinlo kan Oba nikoo? = Abe
3. Maa n weye saaju alo onitan
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kiko alifabeeti

Sub-Topic:
Content:
Kiko álúfábẹ́ ẹ̀ tì yorubá sara patako
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Alo onitan (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Alo onitan: alo ijapa alo olorogun,alo olorun, alo alailorin
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Alo onitan Siwaju si I

Sub-Topic:
Content:
o onitan maa n saaba ni orin ati egbe
O ni ahunpo itan
O n koni iogbon b.a
Alo erin ati ijapa, ijapa, (yanni bo)
Ati Babalawo.
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Kiko alifabeeti (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Kiko álúfábẹ́ ẹ̀ tì yorubá sara patako
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Alo onitan (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Alo onitan: alo ijapa alo olorogun,alo olorun, alo alailorin
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Itan awon akoni ile Yoruba laye atijo ati ode oni

Sub-Topic:
Content:
1. Oruko awon akoni agbegbe akekoo ni aye atijo ati ni ode oni
2. Akitiyan awon akoni ti a ti daruko

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION
THIRD TERM
BASIC 1 BASIC 2 BASIC 3
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: Asa

Topic: Ikini

Sub-Topic:
Content:
Ikin ati ìdáhùn laari n ojo aaro osan ati ale:
- E kaaaro
- E kaasan
- E kaale
WEEK 2

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ikini siwaju sii.

Sub-Topic:
Content:
1. Ikiki ati idahun laarin ojo: aaro Osan Ati ale : e kaaaro, e kaaasan, e kaale
2. Ikini ati idahun fun orisirisi igba to wa ninu odun- Igba ojo, eerun ati oye: e ku ojo, e ku ogbele, e ku oye
WEEK 2

Theme: AÌsaÌ

Topic: Pataki iwa rere

Sub-Topic:
Content:
Awon ipede to n fi iwa rere han b.s. "iwa rere leso eniyan",
"iwa rere omo eniyan",
"Oore lope,
Ika o pe";
"Eni to n se rere ko mura sii...";
"Bi a ba da omi siwuja..."
abbl.
WEEK 3

Theme: Asa

Topic: Ikini (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Ikin ati ìdáhùn laari n ojo aaro osan ati ale:
- E kaaaro
- E kaasan
- E kaale
WEEK 3

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ikini siwaju sii.

Sub-Topic:
Content:
1. Ikiki ati idahun laarin ojo: aaro Osan Ati ale : e kaaaro, e kaaasan, e kaale
2. Ikini ati idahun fun orisirisi igba to wa ninu odun- Igba ojo, eerun ati oye: e ku ojo, e ku ogbele, e ku oye
WEEK 3

Theme: AÌsaÌ

Topic: Asa bi a se n jeun

Sub-Topic:
Content:
Awon liana to to lati tele ti a ba n jeun
Fo owo ki oto jeun
Ma soro bi o ba n jeun
A kii jeun lati inu ikoko
Fo owo nigba ti o ba jeun tan
WEEK 4

Theme: Asa

Topic: Imototo ara eni ati ayika

Sub-Topic: Itoju ara
Content:

WEEK 4

Theme: AÌsaÌ

Topic: Imototo ayika

Sub-Topic:
Content:
Itoju ile ati ayika riro oko e gbe ile ati ayika ile eko gbigba ayika ile ati ile eko fifo ile
WEEK 4

Theme: AÌsaÌ

Topic: Asa bi a se n jeun (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
So idi awon liana wonyi: lati pa ofin imotot mo
WEEK 5

Theme: Asa

Topic: Imototo ara eni ati ayika

Sub-Topic:
Content:
Itoju ile ati ayika ili/ile eko
WEEK 5

Theme: AÌsaÌ

Topic: Imototo ayika (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Itoju ile ati ayika riro oko e gbe ile ati ayika ile eko gbigba ayika ile ati ile eko fifo ile
WEEK 5

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ere omode siwaju si I

Sub-Topic:
Content:
1. Orisiirisii ere omode (Ta lo wa ninu ogba naa kini n l eje, eye meloo tonlongo waye, ekun meran)
2. Bi a se n se won
WEEK 6

Theme: Asa

Topic: Iwa rere

Sub-Topic:
Content:
1. Kikunle /dobale fun agba
2. orisirisi orin to baibawo fagba mu
3. Isododo
4. suuru
WEEK 6

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ifira eni-sipo-omo lakeji

Sub-Topic:
Content:
Iranlowo, ibanikedun, ife, ilawosi, ifira-eni-jin, aanu
WEEK 6

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ere omode siwaju si I (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Anfaani ati iwulo won
2. Ere omode sise
WEEK 7

Theme: Asa

Topic: Iwa rere

Sub-Topic:
Content:
1. iwapele
2. oyaya
3. ikonimora
WEEK 7

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ifira eni-sipo-omo lakeji (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Iranlowo, ibanikedun, ife, ilawosi, ifira-eni-jin, aanu
WEEK 7

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ojuse obi si omo

Sub-Topic:
Content:
Ojuse obi si omo b.a.:ipese - eko to ye kooro-Owo ile iwe- Alaafia pipe-Aso-Ilegbee- Aabo-Fi iwa rere/iwa omolu abi ko awon omo, nipa jije oniwa rere, nitori esin iwaju ni tehin n wo o sare - Pa ofin orile orile ede mo.
WEEK 8

Theme: Asa

Topic: Ojo inu ose

Sub-Topic:
Content:
Awon ojo ninu ose:
- Sunday – aiku
- Monday – aje
- Tuesday- isegun
- Wednessday – ojoru
- Thursday- ojobo
- Friday- eti
- Saturdayet- an Abameta
WEEK 8

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ere Omode

Sub-Topic:
Content:
1. Apeere orisirisii ere omode(bojuboju) okoto, ijakadi, okiti, tita, abbl
2. Bi a se n se won
WEEK 8

Theme: AÌsaÌ

Topic: Awon ohun elo inu ile

Sub-Topic:
Content:
Awon yara inu ile b.a: - Yara ti a n sun
- Yara igbalejo
- Ile idana
- Ile iyagbe
- Baluwe
- Yara ikeru si, abbl.
WEEK 9

Theme: Asa

Topic: Ojo inu ose

Sub-Topic:
Content:
Aiaye ati itan nipa ojo kookan
WEEK 9

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ere Omode (Cont.)

Sub-Topic: 1. Anfaani ati ewu ibe
2. Ere omode sise
Content:

WEEK 9

Theme: AÌsaÌ

Topic: Awon ohun elo inu ile (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Ohun elo to wa ni yara kookan b.a.: - Beedi, tabili, aga, ero asoro magbesi, amohunmaworan, abbl.

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION



VTpass

Free Will Donation

We know times are tough right now, but if you could donate and support us, be rest assured that your great contributions are immensely appreciated and will be for the progress of our work to help us pay for the server cost, domain renewal, and other maintenance costs of the site. Nothing is too small; nothing is too little.

Account Details

BANK: UNITED BANK FOR AFRICA PLC

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2250582550

SWIFT CODE: UNAFNGLA

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: DOLLAR (USD) ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470



BANK: UNITED BANK FOR AFRICA Plc (UBA)

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2042116266

SORT CODE: 033243371

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: NAIRA ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470



Your active support gives strength to our Team and inspires to work. Each donated dollar is not only money for us, but it is also the confidence that you really need our project!
AseiClass is a non-profit project that exists at its founders' expense, it will be difficult to achieve our goals without your help.
Please consider making a donation.
Thank you.
AseiClass Team


Facts about Teachers

● ● ● Teachers Are Great No Controversy.

● ● ● Teachers are like candles, they burn themselves to light others.

● ● ● Teachers don't teach for the money.

● ● ● Every great mind was once taught by some brilliant teachers.

● ● ● Teachers are the second parents we have.

● ● ● If you can write your name, thank your teacher.

Teaching slogans

● ● ● Until the learner learns the teacher has not taught.

● ● ● I hear and forget, I see and remember, I do and know.

● ● ● The good teacher explains. The superior teacher demonstrates. The great teacher inspires.