Recent Scheme of Work on Yoruba Language

Syllabus for Upper Basic




FIRST TERM
BASIC 7 BASIC 8 BASIC 9
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Iro ede (Konsonanti ati Faweli)

Sub-Topic:
Content:
1. Konsonanti: b,d,f,g,gb,h,j,k,l,m,n,p, r,s,ṣ ,t,w,y.
2. Faweli airanmupe: a,e,ẹ,o,ọ,u.
3. Faweli aránmúpè̀̀̀̀ : pè, an, ẹn,in, ọn, un
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìtẹ̀síwájú Iro Ede Ami Ohun

Sub-Topic:
Content:
1. Alaye lori orisi ohun yorùba meteeta ati ami won:
(i) Ohun aarin-(a kii fi i han )
(ii) Ohun oke / ohun ile
2. Faweli ati orisiirisi ami ohun kookan lori faweli kookan. Bi àpẹẹrẹ : à, a, á, è, é, e, ẹ̀ , ẹ,
WEEK 2

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
1. Àyoka ti imo re ko ju ti ojo ori akekoo.
2. Ìbéèrè lori àyoka nipa oye oro inu re ati ilo ede re.
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka ookanleleede-gbeta de egberun (501-1000)

Sub-Topic:
Content:
Onka lati ookanleleedegbeta de egberun (501-1000)
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìtẹ̀síwájú Iro Ede Ami Ohun

Sub-Topic:
Content:
1. Ami ohun lori oro onísilebù kan. B.a: bá, ba, bà, dà, dá, da, abbl
2. Ami ohun lori oro ọlópọ̀ silebu b.a. ọkọ , okó, òkò; pátápátá, pàtàpàtà, kelekèle, àgbagbà abbl.
WEEK 3

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
1. Àyoka ti imo re ko ju ti ojo ori akekoo.
2. Ìbéèrè lori àyoka nipa oye oro inu re ati ilo ede re.
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akaye

Sub-Topic:
Content:
Àyoka ti ko ju ojo ori akekoo lo.
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ìtẹ̀síwájú Iro Ede Ami Ohun

Sub-Topic:
Content:
Ami ohun lori konsonanti aránmú onísilebù kan. Bi apeere: Kònkò , gbangba , konko, atanpako
WEEK 4

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka lati egbaa (2000) De egbaawaa (20,000)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika:
2. Egbaa = 2,000
Egbaàji = 4,000
Egbaàta = 6,000
Egbaawaa = 20,000
3. Eedegbaaji = 3,000
Eedegbaata = 5,000
Eedegbaarin = 7,000
4. Kika onka aarin won.
4,020 – okoo le legbaaji
5,080 – orin le leedegbaata, abbl.
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akotó

Sub-Topic:
Content:
1. Àlàyé ohun ti akotó je
2. Afiwe akotó àtijọ àti ti òde onì :
(i) Faweli: Aiye-ayé Yio-yó /yóó /yóò Enia-eniyan, Abbl.
(ii) Konsonanti: Osogbo-Osogbo Illa-ìlà
(iii) Àmì ohùn : Ogun -oogun Alanu -alaanu
(iv) Yíyàn òro nidii: ẹ,e,ṣ,s – ẹ, ṣ
(v) Pinpin oro: Wipé -wi pe Nigbati -nigba ti
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka: Egberun de egberun meji (egbaa) (1000 - 2000)

Sub-Topic:
Content:
Onka egberun dé egberun meji (egbaa) (1000-2000)
WEEK 5

Theme: EÌdeÌ

Topic: Onka lati egbaa (2000) De egbaawaa (20,000) (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Kika:
2. Egbaa = 2,000
Egbaàji = 4,000
Egbaàta = 6,000
Egbaawaa = 20,000
3. Eedegbaaji = 3,000
Eedegbaata = 5,000
Eedegbaarin = 7,000
4. Kika onka aarin won.
4,020 – okoo le legbaaji
5,080 – orin le leedegbaata, abbl.
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: Àrokò (Oniroyin)

Sub-Topic:
Content:
1. Àkọlé
2. Ìlapa èro
3. Àtúntò ilapa ero
4. Ifaara
5. Ìpín afò
6. Kókó oró inu àrokò
7. Igunle/Asokagba
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: Isori oro

Sub-Topic:
Content:
1. Isori oro:
2. Oro oruko
3. Oro àròpọ̀ oruko
4. Oro apejuwe
5. Oro atọ́kùn
6. Oro asòpò
Àlàyé kikun lori ipo ati ise won ninu gbolohun.
WEEK 6

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akoko siwaju si i

Sub-Topic:
Content:
Agbeyewo ipinnu 1974 ti ijoba apapo lori akoto yorùba (Joint Consultative Committee - JCC)
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Leta kiko

Sub-Topic:
Content:
1. Orisii leta: gbefe àti aigbagbefe
2. Ìyàtọ̀ àárín won.
3. Ìlapa kiko leta gbefe:
• Àdíréẹ̀sì
• Déètì’
• Kiko oro inu leta ki a si pin in si ègé afò bi oti ye
• Asokagba/Agbàlọ̀ gbábò/igunle
4. Ilapa kiko leta aigbagbefe:
• Àdíréẹ̀sì
• Déètì
• Akole
• Oro inu leta ti a pin si ègé afo bi o ti ye
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ihun oro

Sub-Topic:
Content:
1. Bátànì ihun yorùba:
2. F(o, a, e)
3. KF (wa, je)
4. FKF (awon eja, owo, abbl)
WEEK 7

Theme: EÌdeÌ

Topic: Akoko siwaju si i

Sub-Topic:
Content:
Agbeyewo ipinnu 1974 ti ijoba apapo lori akoto yorùba (Joint Consultative Committee - JCC)
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Iseda Orò –Orúkọ

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni oro oruko?
2. Orisi oro oruko meji: aiseda ati eyi ti a ṣẹ̀dà, pelu apeere.
3. Alaye kíkún lori orisiirisi ona iseda oro oruko pelu àpẹẹrẹ
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Orisiirisii gbolohun (ihun)

Sub-Topic:
Content:
1. Gbolohun:
2. Alábọ́ dé
3. Alakanpo
4. Oníbọ̀
WEEK 8

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ise oro arọ́ pò oruko ati oruko ninu gbolohun.

Sub-Topic:
Content:
1. Olùwa:
• Igi wo
• Mo lo si oja
2. Abo fun oro ise:
• Olu ko iwe
• Baba na an
3. Abo fun oro atokun:
• Sade lo si oja
4. Eyan fun oro oruko miiran
• Baba arugbo da?
• Oga mi ko ile.
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Iseda Orò –Orúkọ (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni oro oruko?
2. Orisi oro oruko meji: aiseda ati eyi ti a ṣẹ̀dà, pelu apeere.
3. Alaye kíkún lori orisiirisi ona iseda oro oruko pelu àpẹẹrẹ
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Orisiirisii gbolohun (ihun) (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Gbolohun:
2. Alábọ́ dé
3. Alakanpo
4. Oníbọ̀
WEEK 9

Theme: EÌdeÌ

Topic: Ise oro arọ́ pò oruko ati oruko ninu gbolohun. (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Olùwa:
• Igi wo
• Mo lo si oja
2. Abo fun oro ise:
• Olu ko iwe
• Baba na an
3. Abo fun oro atokun:
• Sade lo si oja
4. Eyan fun oro oruko miiran
• Baba arugbo da?
• Oga mi ko ile.

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION
SECOND TERM
BASIC 7 BASIC 8 BASIC 9
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Sísẹ́ agbeyewo litireso apileko

Sub-Topic:
Content:
1. Koko oro
2. Àhunpò ìtàn
3. Ibùdò itan
4. Èda ìtàn àti ifiwaweda
5. Ìlò – edé
6. Isuyo àso , abbl.
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe àyokà

Sub-Topic:
Content:
1. Itan inu iwe ti a ba ka ni soki
2. Eda itan
3. Ifiwaweda
4. Ibudo itan
5. Àhunpò itan
6. Koko oro to jeyo.
WEEK 2

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe ere onítan

Sub-Topic:
Content:
1. Ibudo itan
2. Àhunpò itan
3. Asà to sùyo
4. Koko oro
5. Ifiwaweda
6. Ilo ede.
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Sísẹ́ agbeyewo litireso apileko (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Koko oro
2. Àhunpò ìtàn
3. Ibùdò itan
4. Èda ìtàn àti ifiwaweda
5. Ìlò – edé
6. Isuyo àso , abbl.
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe àyokà (Ewi)

Sub-Topic:
Content:
1. Awon ewi to wa ninu iwe ti a yan.
2. Koko oro b.a: Iwa eniyan; Awon eda miiran ti kii se eniyan; koko oro to je mo;
oro to n lo lawujo, ikolura esin, Asà, ipo obinrin, Eto iselu, oro aje, Gbogbolomo isako/isabo, Eedi
Akiyesi: Opón dandan lati yan iwe ewi ti o ni awon akoonu koko oro wonyi
3. Ona ede ati isowoloede.
WEEK 3

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe ere onítan (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ibudo itan
2. Àhunpò itan
3. Asà to sùyo
4. Koko oro
5. Ifiwaweda
6. Ilo ede.
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Sísẹ́ agbeyewo litireso alohùn

Sub-Topic:
Content:
Ògangan-ipo:
• Ìtumọ̀ re
• Àbùdá re:
(a) Akopa (osere/olugbo)
(b) Akoko isere
(c) Ibi seré
(d) Iwulo
(e) Ohun elo-orin
(f) Isele
(g) Ifarafojusoro
(h) Ìsáré, orin, ijo
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe àyoka-itan Aroso oloro geere

Sub-Topic:
Content:
1. Ìsọníṣókí isele inu itan ati ibayemu
2. Eko ati koko oro to súyo ati ibayemu oro to nlo lawujo (b.a. Ipo/ipin obinrin lawujo, ikolura esin, omoluabi, itoju ayika, ilera, arun eedi/romoloworomolese abbl)
WEEK 4

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe ewi

Sub-Topic:
Content:
1. Ewi kika
2. Koko oro a-je-mo-oroto- n-lo lawujo/lagbaaye:
• Isetofabo
• Ipo obinrin
• Eto oro-aje
• Ikolura esin/asà
• Ikora-eni-ni ijanu ninu igbesi aye odo, abbl.
3. Ona-ede ati isowolo ede.
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Sísẹ́ agbeyewo litireso alohùn (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
Ògangan-ipo:
• Ìtumọ̀ re
• Àbùdá re:
(a) Akopa (osere/olugbo)
(b) Akoko isere
(c) Ibi seré
(d) Iwulo
(e) Ohun elo-orin
(f) Isele
(g) Ifarafojusoro
(h) Ìsáré, orin, ijo
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe àyoka-itan Aroso oloro geere

Sub-Topic:
Content:
1. Eda itan ati Ifiwaweda won.
2. Ilo ede:
(a) Ona ede:
• Afiwe
• Owe
• Akanlò ede
(b) Àwítúnwí
• Ifiromorisi
• Ifohungbohun abbl
WEEK 5

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe ewi (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ewi kika
2. Koko oro a-je-mo-oroto- n-lo lawujo/lagbaaye:
• Isetofabo
• Ipo obinrin
• Eto oro-aje
• Ikolura esin/asà
• Ikora-eni-ni ijanu ninu igbesi aye odo, abbl.
3. Ona-ede ati isowolo ede.
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Awon isori litireso apileko

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni litireso?
• Ki si ni litireso apileko?
2. Isori litireso, apileko:
• Ewi
• Iwe itan aroso
• Ere onítan
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Orin

Sub-Topic:
Content:
1. Orin ibile to je mo igbeyawo, eremode, oye jije, ìkómojáde ati eko iwa rere.
2. Eko ti a ri ko:
• Pipa ogo obinrin mo
• Gbigba igbe aye rere
• Pataki orin fun idaraya lawujo
• Ibowofagba
• Pataki imototo ara ati ayika.
3. Ewa ede inu awon orin naa.
WEEK 6

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe ewi (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ewi kika
2. Koko oro a-je-mo-oroto- n-lo lawujo/lagbaaye:
• Isetofabo
• Ipo obinrin
• Eto oro-aje
• Ikolura esin/asà
• Ikora-eni-ni ijanu ninu igbesi aye odo, abbl.
3. Ona-ede ati isowolo ede.
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Awon isori litireso apileko (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni litireso?
• Ki si ni litireso apileko?
2. Isori litireso, apileko:
• Ewi
• Iwe itan aroso
• Ere onítan
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Ìsáré/Ajemesin ati Ajemayeye/Alaijemesin

Sub-Topic:
Content:
1. Kini ìsáré ajemesin ati ajemayeye tabi alaijemesin? (ohun pipe/ofun sise ti a n lo ni idi esin orisa kan ati eyi ti a n lo fun ayéye ti ko je mo esin orisa).
2. Ìsáré ajemesin yorùba:
• Ijala
• Esa/iwì egungun
• Iyere ifa
• Sàngó pipe
• Esu pipe, abbl
3. Ìsáré ajemesin tabi alaijemesin:
• Rara
• Ekun iyawo
• Ègé
• Alamo, abbl
WEEK 7

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe itan aroso oloro geere

Sub-Topic:
Content:
1. Ibudo ati àhunpò itan.
2. Asà to súyo
3. Awon koko oro to je
4. Eda itan ati ifiwaweda
5. Ona ede ati ona isowolo-ede.
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Isori-isori litireso alohùn

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni litireso alohùn?
2. Afiwe litireso alohùn ati ti apileko.
3. Awon isori-isori litireso alohùn:
(a) Ewi
- Orin
- Ìṣàlẹ̀
- Arangbo
(b) itan aroso oloro geere
- Alò onítan
- Itan iwase
- Itan akonikayefi
(c) Ere onítan
- Eegun alare
- Odun ibile
(d) Litireso awóhùn ti a da ko sinu iwe (àdàkọ) b.a:
- Ijinle ohun enu
- Ifa-wande
- Abimbola
- Akojopo aló Ijapá
- Apa kinni ati ikeji
- Adeboye Babalola Abbl.
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Ewi Alohùn Arangbo:

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni ewi alohùn arangbo?
2. Arangbo kikun:
• Oriki
• Ese ifa
• Ofo
3. Arangbo kekeke
• Owe
• Alò apamo
• aro
WEEK 8

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe itan aroso oloro geere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ibudo ati àhunpò itan.
2. Asà to súyo
3. Awon koko oro to je
4. Eda itan ati ifiwaweda
5. Ona ede ati ona isowolo-ede.
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Isori-isori litireso alohùn (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni litireso alohùn?
2. Afiwe litireso alohùn ati ti apileko.
3. Awon isori-isori litireso alohùn:
(a) Ewi
- Orin
- Ìṣàlẹ̀
- Arangbo
(b) itan aroso oloro geere
- Alò onítan
- Itan iwase
- Itan akonikayefi
(c) Ere onítan
- Eegun alare
- Odun ibile
(d) Litireso awóhùn ti a da ko sinu iwe (àdàkọ) b.a:
- Ijinle ohun enu
- Ifa-wande
- Abimbola
- Akojopo aló Ijapá
- Apa kinni ati ikeji
- Adeboye Babalola Abbl.
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Ewi Alohùn Arangbo:

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni ewi alohùn arangbo?
2. Arangbo kikun:
• Oriki
• Ese ifa
• Ofo
3. Arangbo kekeke
• Owe
• Alò apamo
• aro
WEEK 9

Theme: Litireso

Topic: Asayan iwe itan aroso oloro geere (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ibudo ati àhunpò itan.
2. Asà to súyo
3. Awon koko oro to je
4. Eda itan ati ifiwaweda
5. Ona ede ati ona isowolo-ede.

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION
THIRD TERM
BASIC 7 BASIC 8 BASIC 9
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 1: Revision
WEEK 2

Theme: AÌsaÌ

Topic: Isedale àti itankale omo yorùba

Sub-Topic:
Content:
1. Isedale yorùba lati odo Oduduwa.
2. Itandale yorùba leyin iku Oduduwa: Owu, Sabee, Kétu, Popo, Oyo, Ijesa, Ijebu, Egba, abbl
3. Lakooko owo eru: Sarò, Amerika, Brazil, Trinidad ati Tobago, Awon Erékùsù Karebia.
WEEK 2

Theme: AÌsaÌ

Topic: Esin ibile

Sub-Topic:
Content:
1. Pataki esin lawujo yorùba.
2. Ipo olodumare.
3. Awon orisa ile yorubá.
4. Esin ode oni:
• Musulumi
• Omoleyin Jesu
WEEK 2

Theme: AÌsaÌ

Topic: Didekun iwa ika si omolakeji

Sub-Topic:
Content:
1. Iwa ika si omolakeji latijo:
• Ikonileru
• Ifinisofa
• Fifi eniyan rubo, abbl.
2. Iwa ika si omolakeji lode oni:
• Jijinigbe
• Ipaniyan
• Lilo omo nilokulo
• Ifomosowo
• Lilu aya/iyawo ile
3. Ona lati dekun re:
• Gbigba alaafia laaye
• Fifi ara-eni si ipo omolakeji
• Agbófinró
• Fifi iya ti o to labe ofin je iru eni ti o ba si hu iru iwa ika, abbl
WEEK 3

Theme: AÌsaÌ

Topic: Isedale àti itankale omo yorùba (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Isedale yorùba lati odo Oduduwa.
2. Itandale yorùba leyin iku Oduduwa: Owu, Sabee, Kétu, Popo, Oyo, Ijesa, Ijebu, Egba, abbl
3. Lakooko owo eru: Sarò, Amerika, Brazil, Trinidad ati Tobago, Awon Erékùsù Karebia.
WEEK 3

Theme: AÌsaÌ

Topic: Esin ibile (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Pataki esin lawujo yorùba.
2. Ipo olodumare.
3. Awon orisa ile yorubá.
4. Esin ode oni:
• Musulumi
• Omoleyin Jesu
WEEK 3

Theme: AÌsaÌ

Topic: Esin ibile yorùba siwaju si i (ohun mimo)

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun mimo ninu esin ibile b.a.:
• Aso funfun
• Efun
• Igba funfun
• Igbin
• Omi ajipon, abbl.
2. Èewo orisa ti o je mo iwa mimo b.a.(otito, ododo), abbl.
WEEK 4

Theme: AÌsaÌ

Topic: Isedale àti itankale omo yorùba (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Isedale yorùba lati odo Oduduwa.
2. Itandale yorùba leyin iku Oduduwa: Owu, Sabee, Kétu, Popo, Oyo, Ijesa, Ijebu, Egba, abbl
3. Lakooko owo eru: Sarò, Amerika, Brazil, Trinidad ati Tobago, Awon Erékùsù Karebia.
WEEK 4

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ogun ati alaafia

Sub-Topic:
Content:
1. Ki ni ogun?; ki si ni idi ti o fi maa n waye?
2. Ogun yorùba laye atijo:
• Oruko ogun b.a. jalumi,kiriji, abbl
• Awon jagunjagun b.a. ibikunle, ogunmola, ogedengbe abbl
• Ohun elo ogun b.a. ofa,oko,ida, ada, ìbon, oogun.
3. Anfaani ogun jija: ona idaabobo ilu eni, lati ko eni leru, abbl.
WEEK 4

Theme: AÌsaÌ

Topic: Owo sise

Sub-Topic:
Content:
1. Oriki owo sise (kara kata)
2. Idi ti owo sise fi se pataki ni ile yorùba
3. Orisiirisii owo ti awon yorùba n se.
4. Ipolowo oja ni ile yorùba.
5. Airisese lode oni ati ipa ti iwo sise le ko.
WEEK 5

Theme: AÌsaÌ

Topic: Awon eya yorùba

Sub-Topic:
Content:
1. Die ninu awon eya to wa b.a: Egba, Ibolò Yewa, Ondó ijesa, Ife, Onkò, Oyo, Ekiti, Ibarapá, Igbomina, Ikalé, Akoko, Awori, Owo, abbl.
2. Afihan ekun ti eya kookan wa ninu maapu.
WEEK 5

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ogun ati alaafia

Sub-Topic:
Content:
1. Aleebu ogun nipa ose ti o n se:
• Da ota sile
• Run ilu
• Fa iyan, abbl.
2. Ona lati dekun ogun jija:
• Yiyago fun aáwọ̀
• Nini suuru, ipamora, iwa pele, ikonimora, ife, ibowo fun omolakeji (omoluabi)
3. Ijiroro ati ìfikùnlukùn gegebi ona ìparí aáwọ̀ ati wiwa alaafia.
WEEK 5

Theme: AÌsaÌ

Topic: Itoju aláboyún

Sub-Topic:
Content:
1. Igbagbo yorùba nipa agan, omo bibi ati abiku.
2. Awon ti oyun nini wa fun (tokotaya).
3. Ona ti a le gba din bibi abiku ku lawujo;
4. Orisiirisii jenotaipu eje to wa ati awon to le fera won;
5. Aajo lati le tete loyun – anfaani kikora-eni-nijanu nipa ibalopo.
6. Bi a se n toju aboyun làtijọ ati lode oni. Atijo :
• Oyun dide, Èewo ki aláboyún, aseje, agbo, abbl. Ode oni:
• Ounje asara lóore, Lilo fun itoju ni ile iwosan (ibile/ijoba) abbl.
WEEK 6

Theme: AÌsaÌ

Topic: Awon eya yorùba (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Die ninu awon eya to wa b.a: Egba, Ibolò Yewa, Ondó ijesa, Ife, Onkò, Oyo, Ekiti, Ibarapá, Igbomina, Ikalé, Akoko, Awori, Owo, abbl.
2. Afihan ekun ti eya kookan wa ninu maapu.
WEEK 6

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ayéye ibile yorùba isomoloruko

Sub-Topic:
Content:
1. Igbagbo yorùba nipa bi oruko se se pataki to (oruko omo ni ijanu omo, oruko a maa ro omo) oruko rere.
2. Eto isolomoloruko b.a. lilo ireke, oyin, aadun, abbl fun iware.
3. Orisiirisi oruko:
• Abiso
• Amutorunwa
• Oriki
• Abiku
• Inagije
• Idile, abbl.
WEEK 6

Theme: AÌsaÌ

Topic: Aroko

Sub-Topic:
Content:
1. Ohun ti aroko je (ona ìbánisọ̀rọ̀ laye atijo ti a le fi we leta kiko lode oni).
2. Orisiirisii aroko: aale, aga, itufu, aroko gan-an.
3. Bi a se n paroko ni aye atijo.
4. Awon ami ìpàrokò ni atijo ati itumo won b.a. owo eyo meta, ikarahun igbin, iye, abbl.
5. Aroko ode oni.
WEEK 7

Theme: AÌsaÌ

Topic: Igbeyawo

Sub-Topic:
Content:
1. Ilana asà igbeyawo ibile eto ifojusode, alárinà, ìjóhen/isihùn, itoro, idana, igbeyawo
2. Igbeyawo lode oni:
• Kóòtù
• Soosi
• Mosalasi
3. Afiwe tibile ati ti tòde oni
4. Anfani ikora eni ni ijanu saaju igbeyawo
5. Ewu ailekora eni nijanu saaju igbeyawo
• Oyun ojiji
• Biba ile omo je
• Arun ajemobaalopo ,atòsì, jeeri-jeeri, eedi(AIDS)
• Igbeyawo airotele/àpàpàndodo.
WEEK 7

Theme: AÌsaÌ

Topic: Ayéye ibile yorùba isomoloruko (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Igbagbo yorùba nipa bi oruko se se pataki to (oruko omo ni ijanu omo, oruko a maa ro omo) oruko rere.
2. Eto isolomoloruko b.a. lilo ireke, oyin, aadun, abbl fun iware.
3. Orisiirisi oruko:
• Abiso
• Amutorunwa
• Oriki
• Abiku
• Inagije
• Idile, abbl.
WEEK 7

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:

WEEK 8

Theme: AÌsaÌ

Topic: Igbeyawo (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ilana asà igbeyawo ibile eto ifojusode, alárinà, ìjóhen/isihùn, itoro, idana, igbeyawo
2. Igbeyawo lode oni:
• Kóòtù
• Soosi
• Mosalasi
3. Afiwe tibile ati ti tòde oni
4. Anfani ikora eni ni ijanu saaju igbeyawo
5. Ewu ailekora eni nijanu saaju igbeyawo
• Oyun ojiji
• Biba ile omo je
• Arun ajemobaalopo ,atòsì, jeeri-jeeri, eedi(AIDS)
• Igbeyawo airotele/àpàpàndodo.
WEEK 8

Theme: AÌsaÌ

Topic: Iranra-eni lowo

Sub-Topic:
Content:
1. Esusu
2. Ajo
3. Owe
4. Aaro
5. Arokodoko
6. Egbe alafowosowopo ode oni.
WEEK 8

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:

WEEK 9

Theme: AÌsaÌ

Topic: Igbeyawo (Cont.)

Sub-Topic:
Content:
1. Ilana asà igbeyawo ibile eto ifojusode, alárinà, ìjóhen/isihùn, itoro, idana, igbeyawo
2. Igbeyawo lode oni:
• Kóòtù
• Soosi
• Mosalasi
3. Afiwe tibile ati ti tòde oni
4. Anfani ikora eni ni ijanu saaju igbeyawo
5. Ewu ailekora eni nijanu saaju igbeyawo
• Oyun ojiji
• Biba ile omo je
• Arun ajemobaalopo ,atòsì, jeeri-jeeri, eedi(AIDS)
• Igbeyawo airotele/àpàpàndodo.
WEEK 9

Theme: AÌsaÌ

Topic: Iranra-eni lowo

Sub-Topic:
Content:
1. Esusu
2. Ajo
3. Owe
4. Aaro
5. Arokodoko
6. Egbe alafowosowopo ode oni.
WEEK 9

Theme:

Topic:

Sub-Topic:
Content:


WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION

WEEK 10: REVISION AND EXAMININATION





We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners


Free Will Donation

We know times are tough right now, but if you could donate and support us, be rest assured that your great contributions are immensely appreciated and will be for the progress of our work to help us pay for the server cost, domain renewal, and other maintenance costs of the site. Nothing is too small; nothing is too little.

Account Details

BANK: UNITED BANK FOR AFRICA PLC

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2250582550

SWIFT CODE: UNAFNGLA

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: DOLLAR (USD) ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470



BANK: UNITED BANK FOR AFRICA Plc (UBA)

ACCOUNT NAME: OFAGBE GODSPOWER GEORGE

ACCOUNT NUMBER: 2042116266

SORT CODE: 033243371

ACCOUNT TYPE: SAVINGS

CURRENCY: NAIRA ACCOUNT

ADDRESS: 1. M. Aruna Close, Ughelli, Delta State, Nigeria

PHONE: +234805 5084784, +234803 5586470



Your active support gives strength to our Team and inspires to work. Each donated dollar is not only money for us, but it is also the confidence that you really need our project!
AseiClass is a non-profit project that exists at its founders' expense, it will be difficult to achieve our goals without your help.
Please consider making a donation.
Thank you.


AseiClass Team

We provide educational resources/materials, curriculum guide, syllabus, scheme of work, lesson note & plan, waec, jamb, O-level & advance level GCE lessons/tutorial classes, on various topics, subjects, career, disciplines & department etc. for all the Class of Learners

Facts about Teachers

● ● ● Teachers Are Great No Controversy.

● ● ● Teachers are like candles, they burn themselves to light others.

● ● ● Teachers don't teach for the money.

● ● ● Every great mind was once taught by some brilliant teachers.

● ● ● Teachers are the second parents we have.

● ● ● If you can write your name, thank your teacher.

Teaching slogans

● ● ● Until the learner learns the teacher has not taught.

● ● ● I hear and forget, I see and remember, I do and know.

● ● ● The good teacher explains. The superior teacher demonstrates. The great teacher inspires.